-
2 Kíróníkà 6:12, 13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Ó wá dúró níwájú pẹpẹ Jèhófà ní iwájú gbogbo ìjọ Ísírẹ́lì, ó sì tẹ́ ọwọ́ rẹ̀ síwájú.+ 13 (Sólómọ́nì ṣe pèpéle bàbà, ó sì gbé e sí àárín àgbàlá.*+ Gígùn rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́* márùn-ún, fífẹ̀ rẹ̀ jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ta; ó sì dúró sórí rẹ̀.) Ó kúnlẹ̀ níwájú gbogbo ìjọ Ísírẹ́lì, ó sì tẹ́ ọwọ́ rẹ̀ sí ọ̀run,+
-