2 Sámúẹ́lì 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́yìn gbogbo nǹkan yìí, Ábúsálómù ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin kan fún ara rẹ̀, ó kó àwọn ẹṣin jọ pẹ̀lú àádọ́ta (50) ọkùnrin tí á máa sáré níwájú rẹ̀.+
15 Lẹ́yìn gbogbo nǹkan yìí, Ábúsálómù ṣe kẹ̀kẹ́ ẹṣin kan fún ara rẹ̀, ó kó àwọn ẹṣin jọ pẹ̀lú àádọ́ta (50) ọkùnrin tí á máa sáré níwájú rẹ̀.+