1 Àwọn Ọba 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí Hírámù gbọ́ ohun tí Sólómọ́nì sọ, inú rẹ̀ dùn gan-an, ó sì sọ pé: “Ìyìn ni fún Jèhófà lónìí, nítorí ó ti fún Dáfídì ní ọlọ́gbọ́n ọmọ tó máa darí ọ̀pọ̀ èèyàn* yìí!”+
7 Nígbà tí Hírámù gbọ́ ohun tí Sólómọ́nì sọ, inú rẹ̀ dùn gan-an, ó sì sọ pé: “Ìyìn ni fún Jèhófà lónìí, nítorí ó ti fún Dáfídì ní ọlọ́gbọ́n ọmọ tó máa darí ọ̀pọ̀ èèyàn* yìí!”+