1 Àwọn Ọba 9:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Èyí ni ìròyìn nípa àwọn tí Ọba Sólómọ́nì ní kó máa ṣiṣẹ́ fún òun+ láti kọ́ ilé Jèhófà,+ ilé* tirẹ̀, Òkìtì,*+ ògiri Jerúsálẹ́mù, Hásórì,+ Mẹ́gídò+ àti Gésérì.+ 1 Àwọn Ọba 9:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ọmọbìnrin Fáráò+ wá láti Ìlú Dáfídì+ sí ilé tirẹ̀ tí Sólómọ́nì kọ́ fún un; lẹ́yìn náà ó mọ Òkìtì.*+
15 Èyí ni ìròyìn nípa àwọn tí Ọba Sólómọ́nì ní kó máa ṣiṣẹ́ fún òun+ láti kọ́ ilé Jèhófà,+ ilé* tirẹ̀, Òkìtì,*+ ògiri Jerúsálẹ́mù, Hásórì,+ Mẹ́gídò+ àti Gésérì.+
24 Ọmọbìnrin Fáráò+ wá láti Ìlú Dáfídì+ sí ilé tirẹ̀ tí Sólómọ́nì kọ́ fún un; lẹ́yìn náà ó mọ Òkìtì.*+