1 Àwọn Ọba 14:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ní ọdún karùn-ún Ọba Rèhóbóámù, Ṣíṣákì+ ọba Íjíbítì wá gbéjà ko Jerúsálẹ́mù.+