1 Àwọn Ọba 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Rèhóbóámù lọ sí Ṣékémù, nítorí gbogbo Ísírẹ́lì ti wá sí Ṣékémù+ láti fi í jọba.+