-
Ẹ́kísódù 10:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ni Fáráò bá yára pe Mósè àti Áárónì, ó sì sọ pé: “Mo ti ṣẹ Jèhófà Ọlọ́run yín, mo sì ti ṣẹ̀ yín. 17 Ẹ jọ̀ọ́, ẹ dárí jì mí lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo yìí, kí ẹ sì bẹ Jèhófà Ọlọ́run yín pé kó mú ìyọnu ńlá yìí kúrò lórí mi.”
-
-
Ìṣe 8:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Ni Símónì bá dá wọn lóhùn pé: “Ẹ bá mi rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sí Jèhófà* kí ìkankan nínú ohun tí ẹ sọ má bàa ṣẹlẹ̀ sí mi.”
-