Àìsáyà 65:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Mo ti tẹ́ ọwọ́ mi sí àwọn alágídí láti àárọ̀ ṣúlẹ̀,+Sí àwọn tó ń rìn ní ọ̀nà tí kò dáa,+Tí wọ́n ń tẹ̀ lé èrò tiwọn;+
2 Mo ti tẹ́ ọwọ́ mi sí àwọn alágídí láti àárọ̀ ṣúlẹ̀,+Sí àwọn tó ń rìn ní ọ̀nà tí kò dáa,+Tí wọ́n ń tẹ̀ lé èrò tiwọn;+