1 Àwọn Ọba 12:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Gbàrà tí gbogbo Ísírẹ́lì gbọ́ pé Jèróbóámù ti pa dà dé, wọ́n pè é wá sí àpéjọ, wọ́n sì fi jọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì.+ Kò sí ìkankan lára àwọn èèyàn náà tó wà lẹ́yìn ilé Dáfídì àfi ẹ̀yà Júdà.+
20 Gbàrà tí gbogbo Ísírẹ́lì gbọ́ pé Jèróbóámù ti pa dà dé, wọ́n pè é wá sí àpéjọ, wọ́n sì fi jọba lórí gbogbo Ísírẹ́lì.+ Kò sí ìkankan lára àwọn èèyàn náà tó wà lẹ́yìn ilé Dáfídì àfi ẹ̀yà Júdà.+