ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 22:42
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 42 Ẹni ọdún márùndínlógójì (35) ni Jèhóṣáfátì nígbà tó jọba, ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Ásúbà ọmọ Ṣílíháì.

  • 2 Kíróníkà 17:3, 4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Jèhófà wà pẹ̀lú Jèhóṣáfátì nítorí pé ó rìn ní àwọn ọ̀nà tí Dáfídì+ baba ńlá rẹ̀ rìn nígbà àtijọ́, kò sì wá àwọn Báálì. 4 Ó wá Ọlọ́run bàbá rẹ̀,+ ó ń pa àṣẹ rẹ̀ mọ́,* kò sì hu ìwà tí Ísírẹ́lì ń hù.+

  • 2 Kíróníkà 18:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Jèhóṣáfátì ní ọrọ̀ àti ògo tó pọ̀ gan-an,+ àmọ́ ó bá Áhábù+ dána.

  • 2 Kíróníkà 19:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Jèhóṣáfátì ń gbé ní Jerúsálẹ́mù, ó sì tún jáde lọ sáàárín àwọn èèyàn náà láti Bíá-ṣébà dé agbègbè olókè Éfúrémù,+ kó lè mú wọn pa dà sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn.+

  • Mátíù 1:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ásà bí Jèhóṣáfátì;+

      Jèhóṣáfátì bí Jèhórámù;+

      Jèhórámù bí Ùsáyà;

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́