2 Kíróníkà 16:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ní àkókò yẹn, Hánáánì+ aríran wá bá Ásà ọba Júdà, ó sì sọ fún un pé: “Nítorí o gbẹ́kẹ̀ lé* ọba Síríà, tí o kò sì gbẹ́kẹ̀ lé* Jèhófà Ọlọ́run rẹ, àwọn ọmọ ogun ọba Síríà ti bọ́ mọ́ ẹ lọ́wọ́.+
7 Ní àkókò yẹn, Hánáánì+ aríran wá bá Ásà ọba Júdà, ó sì sọ fún un pé: “Nítorí o gbẹ́kẹ̀ lé* ọba Síríà, tí o kò sì gbẹ́kẹ̀ lé* Jèhófà Ọlọ́run rẹ, àwọn ọmọ ogun ọba Síríà ti bọ́ mọ́ ẹ lọ́wọ́.+