-
Àwọn Onídàájọ́ 9:53, 54Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
53 Obìnrin kan wá ju ọmọ ọlọ lu Ábímélékì lórí, ó sì fọ́ agbárí rẹ̀.+ 54 Ó bá yára pe ìránṣẹ́ rẹ̀ tó gbé àwọn ohun ìjà rẹ̀, ó sọ fún un pé: “Fa idà rẹ yọ kí o sì pa mí, kí wọ́n má bàa sọ nípa mi pé, ‘Obìnrin ló pa á.’” Ìránṣẹ́ rẹ̀ wá gún un ní àgúnyọ, ó sì kú.
-