1 Kíróníkà 12:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Iye àwọn olórí ọmọ ogun tó ti gbára dì tó wá sọ́dọ̀ Dáfídì ní Hébúrónì+ láti fi í jọba ní ipò Sọ́ọ̀lù nìyí gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Jèhófà pa.+
23 Iye àwọn olórí ọmọ ogun tó ti gbára dì tó wá sọ́dọ̀ Dáfídì ní Hébúrónì+ láti fi í jọba ní ipò Sọ́ọ̀lù nìyí gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí Jèhófà pa.+