Ẹ́kísódù 34:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ṣùgbọ́n kí ẹ wó àwọn pẹpẹ wọn, kí ẹ sì fọ́ àwọn ọwọ̀n òrìṣà wọn túútúú, kí ẹ sì wó àwọn òpó òrìṣà* wọn lulẹ̀.+ 2 Àwọn Ọba 10:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nígbà náà, wọ́n kó àwọn ọwọ̀n òrìṣà+ tó wà ní ilé Báálì jáde, wọ́n sì dáná sun wọ́n lọ́kọ̀ọ̀kan.+ 2 Àwọn Ọba 10:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Bí Jéhù ṣe pa Báálì rẹ́ ní Ísírẹ́lì nìyẹn. 2 Àwọn Ọba 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 (Síbẹ̀, wọn kò jáwọ́ nínú ẹ̀ṣẹ̀ tí ilé Jèróbóámù mú kí Ísírẹ́lì dá.+ Wọ́n ń dá ẹ̀ṣẹ̀ yìí nìṣó,* òpó òrìṣà*+ ṣì wà ní ìdúró ní Samáríà.)
13 Ṣùgbọ́n kí ẹ wó àwọn pẹpẹ wọn, kí ẹ sì fọ́ àwọn ọwọ̀n òrìṣà wọn túútúú, kí ẹ sì wó àwọn òpó òrìṣà* wọn lulẹ̀.+
6 (Síbẹ̀, wọn kò jáwọ́ nínú ẹ̀ṣẹ̀ tí ilé Jèróbóámù mú kí Ísírẹ́lì dá.+ Wọ́n ń dá ẹ̀ṣẹ̀ yìí nìṣó,* òpó òrìṣà*+ ṣì wà ní ìdúró ní Samáríà.)