ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Nọ́ńbà 11:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ni Jèhófà bá sọ fún Mósè pé: “Ṣé ọwọ́ Jèhófà kúrú+ ni? Ó máa ṣojú rẹ báyìí, bóyá ohun tí mo sọ máa ṣẹlẹ̀ sí ọ tàbí kò ní ṣẹlẹ̀.”

  • Àwọn Onídàájọ́ 15:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Ọlọ́run wá mú kí kòtò kan tó wà ní Léhì lanu, omi sì ṣàn jáde látinú rẹ̀.+ Nígbà tó mumi, okun* rẹ̀ pa dà, ó sì sọ jí. Ìdí nìyẹn tó fi pe ibẹ̀ ní Ẹn-hákórè,* èyí tó wà ní Léhì títí dòní.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́