-
Sáàmù 37:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 A ó ṣẹ́ apá àwọn ẹni burúkú,
Àmọ́ Jèhófà yóò ti àwọn olódodo lẹ́yìn.
-
-
Sáàmù 37:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ní àkókò àjálù, ojú kò ní tì wọ́n;
Ní àkókò ìyàn, wọ́n á ní ọ̀pọ̀ oúnjẹ.
-
-
Fílípì 4:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Nítorí náà, Ọlọ́run mi tí ọrọ̀ rẹ̀ kò lópin máa pèsè gbogbo ohun tí ẹ nílò pátápátá+ nípasẹ̀ Kristi Jésù.
-