-
2 Àwọn Ọba 4:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Ni obìnrin náà bá gbé e lọ sókè, ó tẹ́ ẹ sórí ibùsùn èèyàn Ọlọ́run tòótọ́,+ ó ti ilẹ̀kùn mọ́ ọn, ó sì jáde lọ.
-
-
2 Àwọn Ọba 4:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Nígbà tí Èlíṣà wọnú ilé náà, òkú ọmọ náà wà lórí ibùsùn rẹ̀.+
-