Jémíìsì 5:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nítorí náà, ẹ máa jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín+ fún ara yín láìfi ohunkóhun pa mọ́, kí ẹ sì máa gbàdúrà fún ara yín, ká lè mú yín lára dá. Ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ olódodo lágbára gan-an.*+
16 Nítorí náà, ẹ máa jẹ́wọ́ àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín+ fún ara yín láìfi ohunkóhun pa mọ́, kí ẹ sì máa gbàdúrà fún ara yín, ká lè mú yín lára dá. Ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ olódodo lágbára gan-an.*+