-
Ẹ́kísódù 2:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Lẹ́yìn náà, Fáráò gbọ́ ohun tó ṣẹlẹ̀, ó sì fẹ́ pa Mósè; àmọ́ Mósè sá lọ torí Fáráò, ó sì lọ ń gbé ní ilẹ̀ Mídíánì.+ Nígbà tó dé ibẹ̀, ó jókòó sẹ́gbẹ̀ẹ́ kànga kan.
-