-
1 Àwọn Ọba 16:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Áhábù ọmọ Ómírì di ọba lórí Ísírẹ́lì ní ọdún kejìdínlógójì Ásà ọba Júdà, ọdún méjìlélógún (22) ni Áhábù ọmọ Ómírì sì fi ṣàkóso lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà.+
-