2 Sámúẹ́lì 20:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nígbà náà, Jóábù ni olórí gbogbo àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì;+ Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà+ sì jẹ́ olórí àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+ 1 Kíróníkà 27:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Olórí àwùjọ kẹta tí wọ́n yàn láti ṣiṣẹ́ ní oṣù kẹta ni Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà+ olórí àlùfáà, ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnlélógún (24,000) ló sì wà nínú àwùjọ rẹ̀.
23 Nígbà náà, Jóábù ni olórí gbogbo àwọn ọmọ ogun Ísírẹ́lì;+ Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà+ sì jẹ́ olórí àwọn Kérétì àti àwọn Pẹ́lẹ́tì.+
5 Olórí àwùjọ kẹta tí wọ́n yàn láti ṣiṣẹ́ ní oṣù kẹta ni Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà+ olórí àlùfáà, ẹgbẹ̀rún mẹ́rìnlélógún (24,000) ló sì wà nínú àwùjọ rẹ̀.