2 Sámúẹ́lì 7:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 láti ọjọ́ tí mo ti yan àwọn onídàájọ́+ fún àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì. Màá sì fún ọ ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ.+ “‘“Yàtọ̀ síyẹn, Jèhófà sọ fún ọ pé, Jèhófà yóò kọ́ ilé fún ọ.*+ 1 Kíróníkà 17:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 láti ọjọ́ tí mo ti yan àwọn onídàájọ́ fún àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.+ Màá ṣẹ́gun gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ.+ Wò ó, yàtọ̀ síyẹn, ó dájú pé, ‘Jèhófà yóò kọ́ ilé fún ọ.’*
11 láti ọjọ́ tí mo ti yan àwọn onídàájọ́+ fún àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì. Màá sì fún ọ ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ.+ “‘“Yàtọ̀ síyẹn, Jèhófà sọ fún ọ pé, Jèhófà yóò kọ́ ilé fún ọ.*+
10 láti ọjọ́ tí mo ti yan àwọn onídàájọ́ fún àwọn èèyàn mi Ísírẹ́lì.+ Màá ṣẹ́gun gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ.+ Wò ó, yàtọ̀ síyẹn, ó dájú pé, ‘Jèhófà yóò kọ́ ilé fún ọ.’*