1 Àwọn Ọba 20:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Jèhófà bá ọ̀kan lára àwọn ọmọ wòlíì* sọ̀rọ̀,+ ni ó bá sọ fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ pé: “Jọ̀wọ́, lù mí.” Àmọ́ ọkùnrin náà kọ̀, kò lù ú.
35 Jèhófà bá ọ̀kan lára àwọn ọmọ wòlíì* sọ̀rọ̀,+ ni ó bá sọ fún ọ̀rẹ́ rẹ̀ pé: “Jọ̀wọ́, lù mí.” Àmọ́ ọkùnrin náà kọ̀, kò lù ú.