-
1 Àwọn Ọba 18:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Bí Áhábù ṣe rí Èlíjà báyìí, ó sọ fún un pé: “Ṣé ìwọ rèé, ìwọ tí o kó wàhálà ńlá* bá Ísírẹ́lì?”
-
-
Émọ́sì 5:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Wọ́n kórìíra àwọn tó ń báni wí ní ẹnubodè ìlú,
Wọ́n sì kórìíra àwọn tó ń sọ òtítọ́.+
-