-
1 Àwọn Ọba 22:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Torí náà, ọba Ísírẹ́lì kó àwọn wòlíì jọ, nǹkan bí ọgọ́rùn-ún mẹ́rin (400) ọkùnrin, ó sì bi wọ́n pé: “Ṣé kí n lọ bá Ramoti-gílíádì jà tàbí kí n má lọ?” Wọ́n dá a lóhùn pé: “Lọ, Jèhófà yóò sì fi í lé ọba lọ́wọ́.”
-