-
Diutarónómì 12:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ibi tí Jèhófà yàn nínú ọ̀kan lára àwọn ilẹ̀ tó jẹ́ ti ẹ̀yà yín nìkan ni kí ẹ ti rú àwọn ẹbọ sísun yín, ibẹ̀ sì ni kí ẹ ti ṣe gbogbo ohun tí mò ń pa láṣẹ fún yín.+
-