-
1 Sámúẹ́lì 9:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tí àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* Kíṣì bàbá Sọ́ọ̀lù sọ nù, Kíṣì sọ fún Sọ́ọ̀lù ọmọ rẹ̀ pé: “Jọ̀wọ́, mú ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ dání, kí o sì lọ wá àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà.” 4 Ni wọ́n bá gba agbègbè olókè Éfúrémù kọjá àti ilẹ̀ Ṣálíṣà, àmọ́ wọn ò rí wọn. Wọ́n rin ìrìn àjò dé ilẹ̀ Ṣáálímù, àmọ́ àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà ò sí níbẹ̀. Gbogbo ilẹ̀ àwọn ọmọ Bẹ́ńjámínì ni wọ́n dé, síbẹ̀ wọn ò rí wọn.
-