2 Àwọn Ọba 5:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àmọ́, Èlíṣà ní kí ìránṣẹ́ kan lọ sọ fún un pé: “Lọ wẹ̀ nígbà méje+ ní odò Jọ́dánì,+ ara rẹ á pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀, wàá sì mọ́.”
10 Àmọ́, Èlíṣà ní kí ìránṣẹ́ kan lọ sọ fún un pé: “Lọ wẹ̀ nígbà méje+ ní odò Jọ́dánì,+ ara rẹ á pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀, wàá sì mọ́.”