-
2 Àwọn Ọba 5:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Nígbà náà, ọba Síríà sọ pé: “Ó yá, gbéra! Màá fi lẹ́tà kan rán ọ sí ọba Ísírẹ́lì.” Nítorí náà, ó lọ, ó kó tálẹ́ńtì* fàdákà mẹ́wàá àti ẹgbẹ̀rún mẹ́fà (6,000) ẹyọ wúrà àti ìpààrọ̀ aṣọ mẹ́wàá dání.
-