-
Jẹ́nẹ́sísì 19:10, 11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Àmọ́ àwọn ọkùnrin náà nawọ́ mú Lọ́ọ̀tì wọlé sọ́dọ̀ wọn, wọ́n sì ti ilẹ̀kùn. 11 Ṣùgbọ́n wọ́n bu ìfọ́jú lu àwọn ọkùnrin tó wà ní ẹnu ọ̀nà ilé náà, látorí ẹni tó kéré jù dórí ẹni tó dàgbà jù, tó fi jẹ́ pé ó rẹ̀ wọ́n bí wọ́n ṣe ń wá ibi tí ẹnu ọ̀nà wà.
-