Ìdárò 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Àwọn obìnrin aláàánú ti fọwọ́ ara wọn se àwọn ọmọ wọn. + Wọ́n ti di oúnjẹ ọ̀fọ̀ fún wọn nígbà tí ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi wó lulẹ̀.+
10 Àwọn obìnrin aláàánú ti fọwọ́ ara wọn se àwọn ọmọ wọn. + Wọ́n ti di oúnjẹ ọ̀fọ̀ fún wọn nígbà tí ọmọbìnrin àwọn èèyàn mi wó lulẹ̀.+