ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Léfítíkù 13:45, 46
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 45 Ní ti adẹ́tẹ̀ tó ní àrùn náà, kó wọ aṣọ tó ti fà ya, kó má sì tọ́jú irun orí rẹ̀, kó bo irunmú rẹ̀, kó máa ké jáde pé, ‘Aláìmọ́, aláìmọ́!’ 46 Gbogbo ọjọ́ tí àrùn náà bá fi wà lára rẹ̀ ni yóò fi jẹ́ aláìmọ́. Kó lọ máa dá gbé torí pé aláìmọ́ ni. Ẹ̀yìn ibùdó ni kó máa gbé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́