-
1 Àwọn Ọba 21:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, ọ̀ràn kan ṣẹlẹ̀ tó dá lórí ọgbà àjàrà Nábótì ará Jésírẹ́lì. Ọgbà náà wà ní Jésírẹ́lì+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ààfin Áhábù ọba Samáríà.
-