-
2 Àwọn Ọba 9:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nítorí náà, Jéhù dìde, ó wọnú ilé; ìránṣẹ́ náà da òróró sí i lórí, ó sì sọ fún un pé,“Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: ‘Mo fòróró yàn ọ́ ṣe ọba lórí àwọn èèyàn Jèhófà, lórí Ísírẹ́lì.+
-