1 Àwọn Ọba 19:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Torí náà, ó kúrò níbẹ̀, ó sì rí Èlíṣà ọmọ Ṣáfátì níbi tó ti ń fi àwọn akọ màlúù tí wọ́n dì ní méjì-méjì sọ́nà méjìlá (12) túlẹ̀ níwájú rẹ̀, ó sì wà pẹ̀lú ìkejìlá. Nítorí náà, Èlíjà lọ sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì ju ẹ̀wù oyè rẹ̀+ sí i lọ́rùn.
19 Torí náà, ó kúrò níbẹ̀, ó sì rí Èlíṣà ọmọ Ṣáfátì níbi tó ti ń fi àwọn akọ màlúù tí wọ́n dì ní méjì-méjì sọ́nà méjìlá (12) túlẹ̀ níwájú rẹ̀, ó sì wà pẹ̀lú ìkejìlá. Nítorí náà, Èlíjà lọ sọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì ju ẹ̀wù oyè rẹ̀+ sí i lọ́rùn.