2 Àwọn Ọba 8:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Torí náà, ó bá Jèhórámù ọmọ Áhábù lọ láti gbéjà ko Hásáẹ́lì ọba Síríà ní Ramoti-gílíádì,+ ṣùgbọ́n àwọn ará Síríà ṣe Jèhórámù léṣe.+
28 Torí náà, ó bá Jèhórámù ọmọ Áhábù lọ láti gbéjà ko Hásáẹ́lì ọba Síríà ní Ramoti-gílíádì,+ ṣùgbọ́n àwọn ará Síríà ṣe Jèhórámù léṣe.+