-
2 Àwọn Ọba 23:19, 20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Jòsáyà tún mú gbogbo àwọn ilé ìjọsìn tó wà lórí àwọn ibi gíga kúrò ní àwọn ìlú Samáríà,+ èyí tí àwọn ọba Ísírẹ́lì kọ́ láti mú Ọlọ́run bínú, ohun tó ṣe ní Bẹ́tẹ́lì ló ṣe sí àwọn náà.+ 20 Torí náà, ó fi gbogbo àlùfáà àwọn ibi gíga tó wà níbẹ̀ rúbọ lórí àwọn pẹpẹ náà, ó sì sun egungun àwọn èèyàn lórí wọn.+ Lẹ́yìn náà, ó pa dà sí Jerúsálẹ́mù.
-