-
2 Kíróníkà 22:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Nígbà tí Jéhù bẹ̀rẹ̀ sí í mú ìdájọ́ ṣẹ lórí ilé Áhábù, ó rí àwọn ìjòyè Júdà àti àwọn ọmọ àwọn arákùnrin Ahasáyà pẹ̀lú àwọn òjíṣẹ́ Ahasáyà, ó sì pa wọ́n.+
-