1 Kíróníkà 2:55 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Ìdílé àwọn akọ̀wé òfin tó ń gbé ní Jábésì ni àwọn Tírátì, àwọn Ṣímíátì àti àwọn Súkátì. Àwọn yìí ni àwọn Kénì+ tó wá látọ̀dọ̀ Hémátì bàbá ilé Rékábù.+
55 Ìdílé àwọn akọ̀wé òfin tó ń gbé ní Jábésì ni àwọn Tírátì, àwọn Ṣímíátì àti àwọn Súkátì. Àwọn yìí ni àwọn Kénì+ tó wá látọ̀dọ̀ Hémátì bàbá ilé Rékábù.+