-
1 Àwọn Ọba 14:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Nítorí náà, Ọba Rèhóbóámù ṣe àwọn apata bàbà láti fi rọ́pò wọn, ó sì fi wọ́n sí ìkáwọ́ àwọn olórí ẹ̀ṣọ́* tó ń ṣọ́ ẹnu ọ̀nà ilé ọba.
-