1 Àwọn Ọba 19:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kí o fòróró yan Jéhù+ ọmọ ọmọ Nímúṣì ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì, kí o sì yan Èlíṣà* ọmọ Ṣáfátì láti Ebẹli-méhólà ṣe wòlíì ní ipò rẹ.+ 2 Àwọn Ọba 10:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Torí náà, Jèhófà sọ fún Jéhù pé: “Nítorí pé o ṣe dáadáa, tí o sì ṣe ohun tí ó tọ́ lójú mi, bí o ṣe ṣe gbogbo ohun tó wà lọ́kàn mi sí ilé Áhábù,+ àwọn ọmọ rẹ títí dé ìran kẹrin yóò máa jókòó lórí ìtẹ́ Ísírẹ́lì.”+
16 Kí o fòróró yan Jéhù+ ọmọ ọmọ Nímúṣì ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì, kí o sì yan Èlíṣà* ọmọ Ṣáfátì láti Ebẹli-méhólà ṣe wòlíì ní ipò rẹ.+
30 Torí náà, Jèhófà sọ fún Jéhù pé: “Nítorí pé o ṣe dáadáa, tí o sì ṣe ohun tí ó tọ́ lójú mi, bí o ṣe ṣe gbogbo ohun tó wà lọ́kàn mi sí ilé Áhábù,+ àwọn ọmọ rẹ títí dé ìran kẹrin yóò máa jókòó lórí ìtẹ́ Ísírẹ́lì.”+