-
2 Kíróníkà 31:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Wọ́n ń mú àwọn ọrẹ wá tinútinú àti ìdá mẹ́wàá+ pẹ̀lú àwọn ohun mímọ́; Konanáyà ọmọ Léfì ni wọ́n fi sídìí gbogbo nǹkan yìí pé kó jẹ́ alábòójútó, Ṣíméì arákùnrin rẹ̀ sì ni igbá kejì.
-