-
1 Àwọn Ọba 18:11, 12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ìwọ wá ń sọ pé, ‘Lọ sọ fún olúwa rẹ pé: “Èlíjà ti dé.”’ 12 Nígbà tí mo bá kúrò lọ́dọ̀ rẹ, ẹ̀mí Jèhófà yóò gbé ọ lọ+ sí ibi tí mi ò mọ̀, tí mo bá wá sọ fún Áhábù, tí kò sì rí ọ, ó dájú pé yóò pa mí. Bẹ́ẹ̀, ìránṣẹ́ rẹ ti ń bẹ̀rù Jèhófà láti ìgbà èwe rẹ̀ wá.
-