1 Sámúẹ́lì 29:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àwọn Filísínì+ kó gbogbo ọmọ ogun wọn jọ sí Áfékì, nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dó sẹ́gbẹ̀ẹ́ ìsun tí ó wà ní Jésírẹ́lì.+ 1 Àwọn Ọba 20:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún,* Bẹni-hádádì kó àwọn ará Síríà jọ, ó sì lọ sí Áfékì+ láti bá Ísírẹ́lì jà.
29 Àwọn Filísínì+ kó gbogbo ọmọ ogun wọn jọ sí Áfékì, nígbà tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì dó sẹ́gbẹ̀ẹ́ ìsun tí ó wà ní Jésírẹ́lì.+