2 Kíróníkà 26:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Nígbà náà, gbogbo àwọn èèyàn Júdà mú Ùsáyà+ tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16), wọ́n sì fi í jọba ní ipò Amasááyà+ bàbá rẹ̀. 2 Kíróníkà 26:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ni Ùsáyà+ nígbà tó jọba, ọdún méjìléláàádọ́ta (52) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jekoláyà tó wá láti Jerúsálẹ́mù.+
26 Nígbà náà, gbogbo àwọn èèyàn Júdà mú Ùsáyà+ tó jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16), wọ́n sì fi í jọba ní ipò Amasááyà+ bàbá rẹ̀.
3 Ọmọ ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ni Ùsáyà+ nígbà tó jọba, ọdún méjìléláàádọ́ta (52) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jekoláyà tó wá láti Jerúsálẹ́mù.+