-
2 Àwọn Ọba 13:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ní ọdún kẹtàdínlógójì Jèhóáṣì ọba Júdà, Jèhóáṣì+ ọmọ Jèhóáhásì di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà, ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ni ó sì fi ṣàkóso.
-
-
2 Àwọn Ọba 14:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ní ọdún kẹẹ̀ẹ́dógún Amasááyà ọmọ Jèhóáṣì ọba Júdà, Jèróbóámù+ ọmọ Jèhóáṣì ọba Ísírẹ́lì di ọba ní Samáríà, ọdún mọ́kànlélógójì (41) ló sì fi ṣàkóso.
-
-
2 Àwọn Ọba 14:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Níkẹyìn, Jèróbóámù sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, àwọn ọba Ísírẹ́lì; Sekaráyà+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.
-