-
2 Àwọn Ọba 12:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ni Jèhóáṣì ọba Júdà bá kó gbogbo ọrẹ mímọ́ tí Jèhóṣáfátì, Jèhórámù àti Ahasáyà, àwọn baba ńlá rẹ̀, àwọn ọba Júdà, ti yà sí mímọ́ àti àwọn ọrẹ mímọ́ tirẹ̀ àti gbogbo wúrà tí wọ́n rí ní àwọn ibi ìṣúra ilé Jèhófà àti ilé* ọba, ó sì kó wọn ránṣẹ́ sí Hásáẹ́lì ọba Síríà.+ Nítorí náà, ó fi Jerúsálẹ́mù sílẹ̀.
-