2 Kíróníkà 28:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Pékà+ ọmọ Remaláyà pa ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000) ní Júdà ní ọjọ́ kan, gbogbo wọn jẹ́ akíkanjú ọkùnrin, èyí sì ṣẹlẹ̀ nítorí pé wọ́n ti fi Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn sílẹ̀.+
6 Pékà+ ọmọ Remaláyà pa ọ̀kẹ́ mẹ́fà (120,000) ní Júdà ní ọjọ́ kan, gbogbo wọn jẹ́ akíkanjú ọkùnrin, èyí sì ṣẹlẹ̀ nítorí pé wọ́n ti fi Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wọn sílẹ̀.+