2 Kíróníkà 27:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ni Jótámù+ nígbà tó jọba, ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jérúṣà ọmọ Sádókù.+
27 Ẹni ọdún mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (25) ni Jótámù+ nígbà tó jọba, ọdún mẹ́rìndínlógún (16) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Jérúṣà ọmọ Sádókù.+