-
1 Àwọn Ọba 22:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Ìgbà náà ni ọba Ísírẹ́lì sọ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé àwa la ni Ramoti-gílíádì?+ Síbẹ̀, à ń wò, a ò ṣe nǹkan kan láti gbà á lọ́wọ́ ọba Síríà.” 4 Ó wá sọ fún Jèhóṣáfátì pé: “Ṣé wàá tẹ̀ lé mi lọ jà ní Ramoti-gílíádì?” Jèhóṣáfátì dá ọba Ísírẹ́lì lóhùn pé: “Ìkan náà ni èmi àti ìwọ. Ìkan náà ni àwọn èèyàn mi àti àwọn èèyàn rẹ. Ìkan náà sì ni àwọn ẹṣin mi àti àwọn ẹṣin rẹ.”+
-